Àwọn Kókó Inú Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn
Inú wa dùn gan-an láti fi tó o yín létí pé iye àwọn akéde tá a ní báyìí jẹ́ ọ̀kẹ́ mẹ́ẹ̀ẹ́dógún ó lé ẹgbẹ̀rún mẹ́tàlá, ọgọ́rùn-ún márùn àti ọgọ́ta ó dín ẹyọ kan [313,559] lóṣù August 2008. Ìgbà àkọ́kọ́ rèé táwọn akéde máa pọ̀ tó báyìí, èyí tó fi ẹgbẹ̀rún mọ́kànlá àti àádọ́jọ lé mẹ́rin [11,154] ju tọdún tó kọjá.
Iye: Hrs. Mags. R.V. Bi.St.
Aṣá. Àkàn. 447 55,914 13,695 25,442 6,396
Aṣá. Déédéé 29,690 1,586,002 470,613 625,361 181,229
Aṣá. Olù. 13,680 645,051 183,170 217,925 58,273
Akéde 269,742 2,918,631 1,109,829 1,112,428 353,362
ÀRÒPỌ̀ 313,559 Àwọn Tó Ṣèrìbọmi: 244