Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ May 18
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ MAY 18
Orin 24
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
lv-YR orí 5 ìpínrọ̀ 1 sí 6 àti àpótí tó wà lójú ìwé 52 àti 55
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Ẹ́kísódù 30-33
No. 1: Ẹ́kísódù 31:1-18
No. 2: Bí Ọlọ́run àti Kristi Ṣe Jẹ́ Ọ̀kan (td-YR 36D)
No. 3: Ǹjẹ́ O Máa Ń Rántí Láti Dúpẹ́? (lr orí 18)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
Orin 140
5 min: Àwọn ìfilọ̀.
10 min: Orúkọ Ọlọ́run, Ilé Gogoro Tó Lágbára. Àsọyé tá a mú látinú ìwé Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run, ojú ìwé 274 ìpínrọ̀ 6 sí ojú ìwé 275 ìpínrọ̀ 3.
10 min: Ọ̀nà Mẹ́ta Tí Ìnàsẹ̀ Ọ̀rọ̀ Tó Gbéṣẹ́ Pín Sí. Ìjíròrò pẹ̀lú àwùjọ tó dá lórí ìwé, Bí A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Awọn Ìjíròrò Bibeli Kí A Sì Máa Báa Nìṣó, ojú ìwé 2 ìpínrọ̀ 1. Lẹ́yìn tó o bá ti parí ìjíròrò náà, ṣàṣefihàn bá a ṣe lè nasẹ̀ ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ tá a máa lò lóṣù June.
10 min: “Bá A Ṣe Lè Múra Sílẹ̀ fún Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn.” Ìbéèrè àti ìdáhùn.
Orin 28