Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ June 15
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ JUNE 15
Orin 175
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Léfítíkù 6-9
No. 1: Léfítíkù 8:1-17
No. 2: Ọlọ́run Kọ́ Ló Fa Wàhálà Tó Ń Ṣẹlẹ̀ Nínú Ayé (td-YR 31A)
No. 3: Ìdí Tí Kò Fi Yẹ Ká Máa Purọ́ (lr orí 22)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
Orin 25
5 min: Àwọn ìfilọ̀.
10 min: Wàásù Ìhìn Rere. Fi ìtara sọ àsọyé yìí, a gbé e ka ìwé Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run ojú ìwé 279, ìpínrọ̀ 1 sí 4.
10 min: Nígbà Tí Ẹnì Kan Bá Sọ Pé, ‘Mùsùlùmí Ni Mí.’ Ìjíròrò pẹ̀lú àwùjọ, tá a gbé ka ìwé pẹlẹbẹ náà, Bí A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Awọn Ìjíròrò Bibeli Kí A Sì Máa Báa Nìṣó, ojú ìwé 15 àti 16.
10 min: “Máa Múra Sílẹ̀ Dáadáa Tó O Bá Fẹ́ Kọ́ni Lẹ́kọ̀ọ́.” Ìbéèrè àti ìdáhùn.
Orin 68