Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ July 20
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ JULY 20
Orin 73
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Léfítíkù 25-27
No. 1: Léfítíkù 25:39-54
No. 2: Ìdí Tó Fi Nira Láti Máa Ṣe Rere (lr orí 26)
No. 3: Ọlọ́run Fi Àánú Rẹ̀ Hàn (td-YR 31D)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
Orin 46
5 min: Àwọn ìfilọ̀.
8 min: Fífi Kristi Ṣe Ìpìlẹ̀. Àsọyé tá a gbé ka ìwé Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run, ojú ìwé 278, ìpínrọ̀ 1 sí 4.
7 min: Múra Sílẹ̀ Láti Lo Ilé Ìṣọ́ August 1 àti Jí! July–September. Lẹ́yìn tó o bá ti sọ̀rọ̀ ṣókí lórí àwọn ìwé ìròyìn yìí, ní káwọn ará sọ àwọn àpilẹ̀kọ tó ṣeé ṣe kó fa àwọn èèyàn mọ́ra ní ìpínlẹ̀ ìwàásù yín, kí wọ́n sì sọ ìdí tí wọ́n fi rò bẹ́ẹ̀. Ní kí wọ́n sọ ìbéèrè tí wọ́n lè fi bẹ̀rẹ̀ ìjíròrò àti ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tí wọ́n máa fẹ́ láti kà kí wọ́n tó fún ẹni tí wọ́n ń wàásù fún láwọn ìwé ìròyìn náà. Níparí ọ̀rọ̀ rẹ, ṣàṣefihàn ọ̀nà tá a lè gbà lo Ilé Ìṣọ́ àti Jí! náà.
15 min: “Bá A Ṣe Lè Ran Àwọn Akéde Tó Bá Lọ sí Ìjọ Míì Lọ́wọ́.” Ìbéèrè àti ìdáhùn.
Orin 65