Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ August 17
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ AUGUST 17
Orin 225
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
lv-YR orí 8 ìpínrọ̀ 19 sí 26, àpótí tó wà lójú ìwé 94 àti 96
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Númérì 10-13
No. 1: Númérì 13:17-33
No. 2: Ìrànlọ́wọ́ Láti Borí Ìbẹ̀rù (lr orí 30)
□. 3: Gbogbo Kristẹni Tòótọ́ Gbọ́dọ̀ Jẹ́rìí sí Òtítọ́ (td-YR 20A)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
Orin 36
5 min: Àwọn ìfilọ̀.
15 min: Wíwàásù Láti Ilé dé Ilé. Ìjíròrò pẹ̀lú àwùjọ tá a gbé ka ìwé A Ṣètò Wa, ojú ìwé 92, ìpínrọ̀ 3, sí ojú ìwé 95, ìpínrọ̀ 2. Fọ̀rọ̀ wá ọ̀rọ̀ wò lẹ́nu akéde kan tàbí méjì tó ń wàásù láti ilé dé ilé láìka àwọn ìṣòro bí àìlera tàbí ìtìjú sí. Àwọn àǹfààní wo ni wọ́n ti jẹ?
15 min: “Ṣẹ́ Ẹ Ti Múra Sílẹ̀ fún Iléèwé?” Ìbéèrè àti ìdáhùn. Fọ̀rọ̀ wá ọ̀rọ̀ wò lẹ́nu ọ̀dọ́ kan tàbí méjì tí wọ́n ti wàásù níléèwé. Kí ló ràn wọ́n lọ́wọ́? Ní kí wọ́n sọ ìrírí kan.
Orin 221