Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ September 14
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ SEPTEMBER 14
Orin 117
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Númérì 26-29
No. 1: Númérì 27:1-14
No. 2: Kí Ni Ìlànà Èrò Orí, Kí sì Nìdí Tó Fi Ṣe Pàtàkì? (Éfé. 6:4)
No. 3: Jésù Lè Dáàbò Bò Wá (lr orí 33)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
Orin 33
5 min: Àwọn ìfilọ̀.
30 min: “Ṣó O Ti Múra Tán Láti Jẹ Àsè Tẹ̀mí?” Akọ̀wé ìjọ ni kó bójú tó iṣẹ́ yìí. Sọ àpéjọ àgbègbè tá a yan ìjọ yín sí. Jíròrò “Àwọn Ohun Tó Yẹ Ká Fi Sọ́kàn Nípa Àpéjọ Àgbègbè.”
Orin 55