Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ November 30
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ NOVEMBER 30
Orin 139
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
lv orí 13 ìpínrọ̀ 5 sí 15, àpótí tó wà lójú ìwé 150
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Diutarónómì 32-34
No. 1: Diutarónómì 32:1-21
No. 2: Kí Ni “Ọjọ́ Ńlá Jèhófà”? (Sef. 1:14)
No. 3: Àwọn Wo Ni Arákùnrin àti Arábìnrin Wa? (lr orí 43)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
Orin 134
5 min: Àwọn ìfilọ̀.
10 min: Ìwé Tá A Máa Lò Lóṣù December. Ṣàṣefihàn bí ìdílé kan ṣe ń múra bí wọ́n ṣe máa gbé ọ̀rọ̀ wọn kalẹ̀ lóde ẹ̀rí sílẹ̀. Olórí ìdílé náà ṣàṣefihàn bó ṣe máa gbé ọ̀rọ̀ kalẹ̀, lẹ́yìn náà, ẹlòmíì nínú ìdílé náà tún wá ṣàṣefihàn bó ṣe máa gbé ọ̀rọ̀ tiẹ̀ náà kalẹ̀.
10 min: “Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ni Wá Nígbà Gbogbo.” Ìbéèrè àti ìdáhùn.
10 min: “Àpéjọ Àyíká Tó Máa Jẹ́ Ká Lè Máa Dáàbò Bo Ipò Tẹ̀mí Wa.” Ìbéèrè àti Ìdáhùn.
Orin 65