Àwọn Kókó Inú Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn
Ó dùn mọ́ wa láti rí i pé àwọn akéde àti àwọn aṣáájú-ọ̀nà ní Nàìjíríà lo nǹkan bíi mílíọ̀nù mẹ́rin àbọ̀ [4,478,301] wákàtí lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù lóṣù June ọdún 2009. Èyí fi ẹgbàá mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n dín ọgbọ̀n-lé-rúgba lé méjì [49,768] wákàtí ju iye tí wọ́n ròyìn lóṣù June ọdún tó kọjá.