Àwọn Kókó Inú Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn
Ní Oṣù November ọdún 2009, àròpọ̀ iye àwọn aṣáájú-ọ̀nà déédéé tó ròyìn jẹ́ ẹgbẹ̀rún mọ́kàndínlọ́gbọ̀n àti irínwó lé mẹ́sàn-án [29,409]. Èyí fi ẹgbẹ̀rún kan àti àádóje [1,130] ju iye àwọn aṣáájú-ọ̀nà déédéé tó ròyìn ní oṣù November ọdún 2008.