Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ June 21
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ JUNE 21
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: 1 Àwọn Ọba 1-2
No. 1: 1 Àwọn Ọba 1:1-14
No. 2: Báwo Lo Ṣe Lè Dá Àwọn Wòlíì Èké Mọ̀? (td 44A)
No. 3: Báwo Ni Ṣíṣègbọràn sí Ọlọ́run Ṣe Ń Ṣe Wá Láǹfààní Nípa Tara àti Tẹ̀mí?
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
5 min: Àwọn ìfilọ̀.
15 min: Ìwé Tá A Máa Lò Lóṣù July. Ìjíròrò pẹ̀lú àwùjọ. Ní ṣókí, sọ ohun tó wà nínú àwọn ìwé tá a máa lò náà, kó o sì ṣe àṣefihàn kan tàbí méjì.
15 min: “Máa Múra Tán Láti Bẹ̀rẹ̀ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì.” Ìbéèrè àti ìdáhùn. Ṣe àṣefihàn bá a ṣe lè fi ìwé àṣàrò kúkúrú náà Ṣé Wàá Fẹ́ Mọ Òtítọ́? bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì nígbà tá a bá lọ ṣe ìpadàbẹ̀wò sọ́dọ̀ ẹni tó gba ìwé tá a máa lò lóṣù July.