Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ August 9
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ AUGUST 9
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
cf orí 8 ìpínrọ̀ 18 sí 22 àti àpótí tó wà lójú ìwé 86
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: 1 Àwọn Ọba 21-22
No. 1: 1 Àwọn Ọba 22:1-12
No. 2: Hẹ́ẹ̀lì Kì Í Ṣe Ibi Ìdánilóró (td 16A)
No. 3: Kí La Rí Kọ́ Látara Èlíjà Nípa Àdúrà? (Ják. 5:18)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
5 min: Àwọn ìfilọ̀.
10 min: Kí Ni Àwọn Àfojúsùn Rẹ Nípa Tẹ̀mí? Ìjíròrò pẹ̀lú àwùjọ tá a gbé ka ìwé A Ṣètò Wa, ojú ìwé 117, ìpínrọ̀ 1 sí ìparí orí náà. Ní káwọn ará sọ ọ̀nà tí àwọn òbí wọn tàbí àwọn ẹlòmíì gbà ràn wọ́n lọ́wọ́ kí wọ́n lè fi iṣẹ́ ìsìn alákòókò kíkún ṣe àfojúsùn wọn.
20 min: “O Lè Jẹ́rìí Láìjẹ́-bí-Àṣà!”—Apá Kìíní. Ẹ jíròrò ìpínrọ̀ 1 sí 8 lọ́nà ìbéèrè àti ìdáhùn. Ṣe àṣefihàn kan tàbí méjì lára àwọn àbá tó wà nínú àpilẹ̀kọ náà.