Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ September 13
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ SEPTEMBER 13
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: 2 Àwọn Ọba 16-18
No. 1: 2 Àwọn Ọba 17:1-11
No. 2: Lílo Ère Nínú Ìjọsìn Jẹ́ Ẹ̀gàn sí Ọlọ́run (td 9A)
No. 3: Ǹjẹ́ Bíbélì Sọ Pé Ká Gba Ọlọ́run Gbọ́ Láìjanpata?
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
5 min: Àwọn ìfilọ̀.
10 min: Àǹfààní Ńlá Ló Jẹ́ fún Wa Láti Jẹ́ Òjíṣẹ́ Tó Ń Wàásù Ìhìn Rere. Fi ìtara sọ àsọyé yìí. A gbé e ka ìwé A Ṣètò Wa, ojú ìwé 77 ìpínrọ̀ 2 sí 78, ìpínrọ̀ 2.
20 min: “Bíbélì Máa Ń Mú Kí Ayé Ẹni Dára.” Ìbéèrè àti ìdáhùn. Gẹ́gẹ́ bí àfidípò, ẹ lo àpilẹ̀kọ náà, “Bíbélì Máa Ń Sọni Dèèyàn Rere,” tó wà nínú Ilé Ìṣọ́ November 1, 2009, ojú ìwé 26 sí 30. Alàgbà ni kó sọ àsọyé yìí.