Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ September 27
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ SEPTEMBER 27
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: 2 Àwọn Ọba 23-25
No. 1: 2 Àwọn Ọba 23:1-7
No. 2: Jèhófà Nìkan Ló Yẹ Ká Jọ́sìn (td 9D)
No. 3: Àwọn Ọ̀nà Wo Làwọn Kristẹni Tòótọ́ Lè Gbà Mú Kí Ìmọ́lẹ̀ Wọn Máa Tàn? (Mát. 5:14-16)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
5 min: Àwọn ìfilọ̀.
15 min: Múra Sílẹ̀ Láti Lo Àwọn Ìwé Ìròyìn Ti Oṣù October. Ìjíròrò. Fi ìṣẹ́jú kan tàbí méjì sọ̀rọ̀ lórí ohun tó wà nínú àwọn ìwé ìròyìn náà. Lẹ́yìn náà, yan àpilẹ̀kọ méjì tàbí mẹ́ta, kó o sì ní kí àwùjọ sọ àwọn ìbéèrè àti ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tí wọ́n lè fi gbé ọ̀rọ̀ wọn kalẹ̀. Ṣe àṣefihàn bá a ṣe lè lo ìwé ìròyìn kọ̀ọ̀kan.
15 min: “Ṣé Wàá Bẹ̀rẹ̀ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ní Oṣù October?” Ìbéèrè àti ìdáhùn. Ṣe àṣefihàn kan tàbí méjì.