Àwọn Kókó Inú Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn
Àwọn akéde tí ìpíndọ́gba wọn jẹ́ ẹgbàá mẹ́tàdínlọ́gọ́jọ àti ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rún ó lé kan [294, 901] ló ròyìn títí di oṣù April 2010. Inú wa dùn pé ẹgbẹ̀rún mẹ́ta àti ọ̀rìndínlẹ́gbẹ̀rin ó lé méjì [3,722] ni èyí fi lé sí ìpíndọ́gba àwọn tó ròyìn ní ọdún iṣẹ́ ìsìn tó kọjá. ‘Ǹjẹ́ kí ọwọ́ wa má ṣe rọ jọwọrọ’ bí òpin ti ń sún mọ́lé.—Sef. 3:16.