Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ January 31
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ JANUARY 31
Orin 99 àti Àdúrà
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
cf orí 17 ìpínrọ̀ 1 sí 9 (25 min)
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Nehemáyà 1-4 (10 min)
No. 1: Nehemáyà 2:11-20 (ìṣẹ́jú 4 tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
No. 2: Ìyè Àìnípẹ̀kun Kì Í Ṣe Àlá Lásán—td 33A (5 min)
No. 3: Àwọn Ọ̀nà Tá À Ń Gbà Ṣègbọràn sí Ọ̀rọ̀ Jésù Nínú Mátíù 22:21 (5 min)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
5 min: Àwọn ìfilọ̀.
20 min: “Ìrànlọ́wọ́ fún Àwọn Ìdílé.”—Apá 2. (Ìpínrọ̀ 7 sí 13) Ìbéèrè àti ìdáhùn. Ní kí àwùjọ sọ bí ìdílé wọn ṣe jàǹfààní nígbà tí wọ́n tẹ̀ lé àwọn kan lára àwọn àbá tó wà lójú ìwé 6.
10 min: “Kọ́ Àwọn Ọmọ Rẹ Láti Di Òjíṣẹ́.” Ìbéèrè àti ìdáhùn. Ní kí àwùjọ sọ àwọn ọ̀nà pàtó tí àwọn òbí wọn gbà ràn wọ́n lọ́wọ́ láti ní àwọn àfojúsùn kí ọwọ́ wọn sì tẹ àwọn àfojúsùn wọn lẹ́nu iṣẹ́ òjíṣẹ́ ní ṣíṣẹ̀-n-tẹ̀lé.
Orin 88 àti Àdúrà