Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ March 14
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ MARCH 14
Orin 101 àti Àdúrà
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
bt orí 1 ìpínrọ̀ 1 sí 9, lẹ́tà tó wà lójú ìwé 2 (25 min.)
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Jóòbù 1-5 (10 min.)
No. 1: Jóòbù 3:1-26 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
No. 2: Ẹ̀kọ́ Wo La Lè Rí Kọ́ Látinú Àpẹẹrẹ Àwọn Ọmọbìnrin Sélóféhádì?—Núm. 36:10-12 (5 min.)
No. 3: Ojúṣe Àwọn Òbí sí Àwọn Ọmọ—td 19D (5 min.)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
5 min: Àwọn ìfilọ̀.
15 min: Sísin Jèhófà Ló Ń Sọni Di Ọlọ́rọ̀. (Òwe 10:22) Ìjíròrò tó dá lórí Ilé Ìṣọ́ September 1, 2009, ojú ìwé 4 sí 7. Lẹ́yìn tó o bá ti jíròrò ìrírí kọ̀ọ̀kan, ní kí àwọn ará sọ ẹ̀kọ́ tí wọ́n rí kọ́ nínú ìrírí náà.
15 min: “Ẹ Jẹ́ Ká Fi Ìmọrírì Wa Hàn.” Ìbéèrè àti ìdáhùn. Sọ ètò tí ìjọ ṣe nípa Ìrántí Ikú Kristi.
Orin 8 àti Àdúrà