Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ April 11
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ APRIL 11
Orin 44 àti Àdúrà
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
bt orí 2 ìpínrọ̀ 8 sí 15 (25 min.)
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Jóòbù 21-27 (10 min.)
No. 1: Jóòbù 25:1–26:14 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
No. 2: Ìdí Tí Kò Fi Yẹ Ká Máa Lo Àgbélébùú Nínú Ìjọsìn (5 min.)
No. 3: Bí Amágẹ́dọ́nì Ṣe Fi Ìfẹ́ Tí Ọlọ́run Ní Hàn—td 4B (5 min.)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
5 min: Àwọn Ìfilọ̀. Sọ fún àwọn ará nípa bí ìwé ìkésíni síbi Ìrántí Ikú Kristi tá à ń pín ṣe ń lọ sí ní ìpínlẹ̀ ìwàásù yín.
10 min: Fún Irúgbìn Rẹ, Má Ṣe Jẹ́ Kí Ọwọ́ Rẹ Sinmi. (Oníw. 11:6) Ìjíròrò tá a gbé ka Ilé Ìṣọ́ April 15, 2004, ojú ìwé 24 sí 26 àti Ilé Ìṣọ́ October 1, 2004, ojú ìwé 8. Lẹ́yìn tó o bá ti jíròrò ìrírí kọ̀ọ̀kan (bí àkókò bá ṣe wà sí), ní kí àwọn ará sọ ẹ̀kọ́ tí wọ́n rí kọ́.
10 min: Bá A Ṣe Lè Fi Lẹ́tà Jẹ́rìí. Ìjíròrò tá a gbé ka ìwé Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjoba Ọlọ́run ojú ìwé 71 sí 73.
10 min: “A Máa Jẹ́rìí Lọ́nà Tó Múná Dóko.” Ìbéèrè àti ìdáhùn.
Orin 8 àti Àdúrà