Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ June 20
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ JUNE 20
Orin 63 àti Àdúrà
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
bt orí 5 ìpínrọ̀ 9 sí 16, àti àpótí tó wà lójú ìwé 41 sí 42 (25 min.)
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Sáàmù 45-51 (10 min.)
No. 1: Sáàmù 48:1–49:9 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
No. 2: Kí Ni Ṣọ́ọ̀ṣì Kristẹni?—td 43A (5 min.)
No. 3: Níwọ̀n Bí Ìyè Ti Jẹ́ Ẹ̀bùn, Kí Nìdí Tó Fi Pọn Dandan Pé Ká Ṣiṣẹ́ Ìgbàlà Wa Yọrí?—Róòmù 6:23; Fílí. 2:12 (5 min.)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
5 min: Àwọn Ìfilọ̀.
10 min: Ìwé Tá A Máa Lò Lóṣù July. Ìjíròrò pẹ̀lú àwùjọ. Ní ṣókí, sọ ohun tó wà nínú àwọn ìwé tá a máa lò náà, kó o sì ṣe àṣefihàn kan tàbí méjì.
10 min: Láti Ẹnu Àwọn Ìkókó. (Mát. 21:15, 16) Ìjíròrò tó dá lórí Ilé Ìṣọ́ January 1, 1995 ojú ìwé 24. Lẹ́yìn tẹ́ ẹ bá ti jíròrò ìrírí kọ̀ọ̀kan, ní kí àwọn ará sọ̀rọ̀ lórí ẹ̀kọ́ tí wọ́n rí kọ́.
10 min: “Ìjẹ́rìí Òpópónà Tó Gbéṣẹ́.” Ìbéèrè àti ìdáhùn. Alábòójútó iṣẹ́ ìsìn ni kó ṣe iṣẹ́ yìí. Sọ bí àwọn ará ṣe lè lo ohun tó wà nínú àpilẹ̀kọ yìí ní ìpínlẹ̀ ìwàásù ìjọ yín. Ní ṣókí, ṣe àṣefihàn kókó kan tàbí méjì látinú àpilẹ̀kọ náà.
Orin 107 àti Àdúrà