Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ August 15
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ AUGUST 15
Orin 39 àti Àdúrà
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
bt orí 8 ìpínrọ̀ 1 sí 7, àti àpótí tó wà lójú ìwé 61 sí 62 (25 min.)
Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Sáàmù 102-105 (10 min.)
No. 1: Sáàmù 105:1-24 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
No. 2: Ìdí Tí Kò Fi Yẹ Ká Jẹ́ Kí Ọkàn Wa Fà Sí Ohun Táa Ti Yááfì Ká Lè Sin Jèhófà—Lúùkù 9:62 (5 min.)
No. 3: Ṣé Òkú Lè Pa Ọ́ Lára?—td 24B (5 min.)
Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
5 min: Àwọn Ìfilọ̀.
10 min: Ran Àwọn Olùfìfẹ́hàn Lọ́wọ́ Láti Tẹ̀ Síwájú. Àsọyé tá a gbé ka ìwé Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run, ojú ìwé 187, ìpínrọ̀ 6, sí ojú ìwé 188, ìpínrọ̀ 3.
20 min: “A Ṣètò Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Láti Wàásù Ìhìn Rere.” Ìbéèrè àti Ìdáhùn. Ní ṣókí, lo ìsọfúnni tó wà ní ìpínrọ̀ kìíní láti fi nasẹ̀ ìjíròrò náà, kó o sì lo èyí tó wà ní ìpínrọ̀ tó gbẹ̀yìn láti fi kádìí ìjíròrò náà.
Orin 47 àti Àdúrà