Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ October 17
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ OCTOBER 17
Orin 85 àti Àdúrà
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
bt orí 11, ìpínrọ̀ 5 sí 12, àti àpótí tó wà lójú ìwé 89 (25 min.)
Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Òwe 12-16 (10 min.)
No. 1: Òwe 15:1-17 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
No. 2: Báwo Ni Àdúrà Tó Ṣètẹ́wọ́gbà Ṣe Dà Bíi Tùràrí Olóòórùn Dídùn sí Jèhófà?—Sm. 141:2; Ìṣí. 5:8 (5 min.)
No. 3: Báwo Ni Ìwòsàn Tẹ̀mí Ti Ṣe Pàtàkì Tó?—td 32A (5 min.)
Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
5 min: Àwọn Ìfilọ̀.
10 min: Kí La Rí Kọ́? Ìjíròrò. Ẹ ka Mátíù 5:11, 12, 14-16, 23, 24. Ṣàgbéyẹ̀wò bí àwọn ẹsẹ Ìwé Mímọ́ yìí ṣe lè ràn wá lọ́wọ́ lẹ́nu iṣẹ́ òjíṣẹ́ wa.
10 min: Jẹ́ Kí Ẹni Tí Ò Ń Bá Sọ̀rọ̀ Fojú Ara Rẹ̀ Rí I. Ìjíròrò tá a gbé ka ìwé Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run, ojú ìwé 145. Ṣe àṣefihàn kan, kí akéde kan lọ ṣe ìpadàbẹ̀wò ẹnì kan tí kò sí orúkọ Ọlọ́run nínú ìtumọ̀ Bíbélì tó wà lọ́wọ́ rẹ̀.
10 min: “Má Ṣe Fà Sẹ́yìn.” Ìbéèrè àti ìdáhùn. Ní kí àwọn àgbàlagbà àti àwọn ọmọdé sọ ìrírí tí wọ́n ní nígbà tí wọ́n ń jẹ́rìí ní iléèwé.
Orin 80 àti Àdúrà