Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ December 19
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ DECEMBER 19
Orin 125 àti Àdúrà
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
bt orí 14 ìpínrọ̀ 6 sí 10, àti àpótí tó wà lójú ìwé 110 (25 min.)
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Aísáyà 11-16 (10 min.)
No. 1: Aísáyà 13:1-16 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
No. 2: Ìdí Tá A Fi Ń Rìn Nípa Ìgbàgbọ́, Tí Kì í Sì Ṣe Nípa Ohun Tí A Rí—2 Kọ́r. 5:7 (5 min.)
No. 3: Ojú Tí Àwa Kristẹni Fi Ń Wo Àwọn Ayẹyẹ—td 38A
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
10 min: Àwọn Ìfilọ̀. Sọ ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ tá a máa lò lóṣù January, kí o sì ṣe àṣefihàn kan.
15 min: Wàásù Ní Àsìkò Tí Ó Kún Fún Ìdààmú. (2 Tím. 4:2) Ìjíròrò pẹ̀lú àwùjọ tá a gbé ka Ilé Ìṣọ́ April 1, 1999, ojú ìwé 8. Ní kí àwọn ará sọ ẹ̀kọ́ tí wọ́n rí kọ́.
10 min: Àpótí Ìbéèrè. Alábòójútó iṣẹ́ ìsìn ni kó bójú tó ìjíròrò yìí.
Orin 92 àti Àdúrà