Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ December 26
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ DECEMBER 26
Orin 123 àti Àdúrà
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
bt orí 14 ìpínrọ̀ 11 sí 20 (25 min.)
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Aísáyà 17-23 (10 min.)
Àtúnyẹ̀wò Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run (20 min.)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
5 min: Àwọn Ìfilọ̀. Jíròrò àpilẹ̀kọ náà, “Ọ̀nà Tó Dára Láti Gbádùn Àwọn Orin Ìjọba Ọlọ́run.”
15 min: Bí A Ṣe Lè Lo Ìwé Náà, Bí A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Awọn Ìjíròrò Bibeli Kí A Sì Máa Báa Nìṣó. Ìjíròrò tá a gbé ka ìwé kékeré náà, Bí A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Awọn Ìjíròrò Bibeli Kí A Sì Máa Báa Nìṣó, ojú ìwé 2, 7 àti 8. Ṣàlàyé bí a ṣe lè lo ìwé yìí. Ṣe àṣefihàn kan tàbí méjì.
15 min: Kí La Rí Kọ́? Ìjíròrò. Ka Ìṣe 10:1-35. Jíròrò bí àkọsílẹ̀ yìí ṣe lè ràn wá lọ́wọ́ lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù wa.
Orin 63 àti Àdúrà