Àwọn Kókó Inú Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn
Ní oṣù February, àwọn akéde tó ròyìn jẹ́ ọ̀kẹ́ mẹ́ẹ̀ẹ́dógún ó lé ẹ̀ẹ́dégbèje àti mọ́kàn-dín-nírínwó [313,399]. Èyí fi hàn pé ẹgbẹ̀rún méje, irínwó àti mọ́kàndínláàádọ́ta [7,449] ni iye akéde tá a ní láàárín oṣù mẹ́fà àkọ́kọ́ lọ́dún iṣẹ́ ìsìn yìí fi ju ti ọdún iṣẹ́ ìsìn tó kọjá lọ.