Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ August 12
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ AUGUST 12
Orin 112 àti Àdúrà
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
jr orí 13 ìpínrọ̀ 1 sí 7 (30 min.)
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Róòmù 5-8 (10 min.)
No. 1: Róòmù 6:21–7:12 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
No. 2: Ìbatisí Kò Wẹ Ẹ̀ṣẹ̀ Nù—td 17B (5 min.)
No. 3: Lílépa Nǹkan Tara Dípò Tẹ̀mí Ń Yọrí sí Wàhálà—Mát. 6:33; 1 Tím. 6:10 (5 min.)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
10 min: “Fetí Sílẹ̀ Kó O sì Kẹ́kọ̀ọ́.” Ìbéèrè àti ìdáhùn.
10 min: “Ìpolongo Tó Méso Rere Jáde.” Ìjíròrò. Fún àwọn ará ní ẹ̀dà kọ̀ọ̀kan ìwé ìkésíni náà, bí ẹ bá ti rí i gbà, kó o sì jíròrò ohun tó wà nínú rẹ̀. Sọ ìgbà tẹ́ ẹ máa bẹ̀rẹ̀ sí í pín ìwé náà ní ìpínlẹ̀ ìwàásù yín àti ètò tí ìjọ ti ṣe láti kárí ìpínlẹ̀ ìwàásù yín. Ní ṣókí, ṣe àṣefihàn bá a ṣe lè fún àwọn èèyàn ní ìwé ìkésíni náà.
10 min: “Fi Ìwà Rẹ Gbé Orúkọ Ọlọ́run Ga.” Ìbéèrè àti ìdáhùn. Jíròrò èyí tó kan ìjọ yín nínú “Àwọn Ohun Tó Yẹ Ká Fi Sọ́kàn Nípa Àpéjọ Àgbègbè Ọdún 2013” lójú ìwé 4 àti 5.
Orin 121 àti Àdúrà