Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ October 14
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ OCTOBER 14
Orin 32 àti Àdúrà
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
jr orí 15 ìpínrọ̀ 7 sí 12 (30 min.)
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Fílípì 1-4–Kólósè 1-4 (10 min.)
No. 1: Fílípì 3:17–4:9 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
No. 2: Ṣé Pétérù Ni Àpáta Náà?—td 43B (5 min.)
No. 3: Báwo Ni Àdúrà Ṣe Lè Ràn Wá Lọ́wọ́ Ká Lè Borí Ìdẹwò?—Lúùkù 11:9-13; Ják. 1:5 (5 min.)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
15 min: Bá A Ṣe Wà Níṣọ̀kan Kárí Ayé Ń Fi Ìyìn fún Jèhófà. Àsọyé tá a gbé ka ìwé A Ṣètò Wa, ojú ìwé 165, ìpínrọ̀ 2, sí ojú ìwé 168 ìpínrọ̀ 1. Ní kí àwọn ará sọ àwọn ìrírí mélòó kan tí ètò Ọlọ́run ti tẹ̀ jáde, tó fi hàn bí ìṣọ̀kan àti ìfẹ́ tó wà láàárín àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣe jẹ́rìí fáwọn èèyàn.
15 min: “Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Ṣàǹfààní fún Kíkọ́ni.” Ìbéèrè àti ìdáhùn. Sọ ọjọ́ tẹ́ ẹ máa lọ sí àpéjọ àyíká yín, tẹ́ ẹ bá ti mọ̀ ọ́n.
Orin 53 àti Àdúrà