Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ November 18
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ NOVEMBER 18
Orin 20 àti Àdúrà
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
jl Ẹ̀kọ́ 8 sí 10 (30 min.)
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Hébérù 9-13 (10 min.)
No. 1: Hébérù 10:19-39 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
No. 2: Ǹjẹ́ Ó Yẹ Káwa Kristẹni Máa Lo Àgbélébùú?—td 2B (5 min.)
No. 3: Bá A Ṣe Lè Tu Àwọn Ẹlòmíì Nínú—Róòmù 15:4; 2 Kọ́r. 1:3, 4 (5 min.)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
10 min: Àpótí Ìbéèrè. Ìjíròrò.
10 min: “Ìdí Tí Mo Fi Wá Síbí Ni Pé . . . ” Ìjíròrò. Lẹ́yìn náà, sọ ìwé tá a máa lò lóde ẹ̀rí ní oṣù December, kí o sì lo àwọn àbá tó wà nínú àpilẹ̀kọ náà láti ṣe àṣefihàn kan tàbí méjì.
10 min: Jèhófà Máa Ń Gbọ́ Àdúrà Àwọn Ìránṣẹ́ Rẹ̀. (1 Jòh. 3:22) Ìjíròrò tó dá lé ìwé Ọdọọdún 2013, ojú ìwé 91 ìpínrọ̀ 2 sí ojú ìwé 92 ìpínrọ̀ 1 àti ojú ìwé 108 sí 109. Ní kí àwọn ara sọ ẹ̀kọ́ tí wọ́n kọ́.
Orin 56 àti Àdúrà