Àwọn Ìfilọ̀
◼ Ìwé tá a máa lò ní November àti December: Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an?, Ṣé Wàá Fẹ́ Mọ Òtítọ́?, tàbí ìwé àṣàrò kúkúrú èyíkéyìí tí ìjọ bá ní lọ́wọ́. January àti February: Ìròyìn Ayọ̀ Látọ̀dọ̀ Ọlọ́run!” tàbí ìwé pẹlẹbẹ olójú ewé 32 èyíkéyìí tẹ́ ẹ bá ní lọ́wọ́.