ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • km 10/14 ojú ìwé 4
  • Bí A Ṣe Lè Máa Fi Sọ́kàn Pé Iṣẹ́ Ìwàásù Jẹ́ Kánjúkánjú

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Bí A Ṣe Lè Máa Fi Sọ́kàn Pé Iṣẹ́ Ìwàásù Jẹ́ Kánjúkánjú
  • Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2014
  • Ìsọ̀rí
  • Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ NOVEMBER 3
Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2014
km 10/14 ojú ìwé 4

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ November 3

Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ NOVEMBER 3

Orin 79 àti Àdúrà

Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:

cl orí 15 ìpínrọ̀ 11 sí 19 (30 min.)

Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:

Bíbélì kíkà: Diutarónómì 14-18 (10 min.)

No. 1: Diutarónómì 15:16–16:8 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

No. 2: Bíbélì Jẹ́ Ká Mọ̀ Pé Màríà Kì Í Ṣe “Wúńdíá Títí Lọ”—td 23B (5 min.)

No. 3: Bí A Ṣe Lè Rántí Jèhófà àti Ọmọ Rẹ̀—lr orí 37 (5 min.)

Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:

Orin 103

10 min: Ran Àwọn Ọmọdé Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Múra Òde Ẹ̀rí Sílẹ̀. Ìjíròrò. Fi fídíò náà, Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà—Jẹ́ Ká Lọ sí Òde Ẹ̀rí han àwọn ará. (Lọ sí ìkànnì jw.org/yo, wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN ỌMỌDÉ.) Bi àwọn ọmọdé láwọn ìbéèrè yìí: Ṣé gbogbo yín lẹ ní báàgì òde ẹ̀rí? Kí lẹ máa ń kó sínú báàgì òde ẹ̀rí náà? Kí ni Tósìn kọ́kọ́ fi sínú báàgì òde ẹ̀rí rẹ̀? Kí lohun míì tó tún nílò? Lẹ́yìn tó ti kó àwọn ìwé sínú báàgì rẹ̀, nǹkan pàtàkì wo ni òun àti ìyá rẹ̀ lọ ṣe? Ní kí ọmọdé kan ṣe àṣefihàn bó ṣe máa fi ìwé ìròyìn lọni lóde ẹ̀rí.

10 min: Bí Àwọn Kan Ṣe Wàásù Ọ̀rọ̀ Náà Lọ́nà Tó Fi Hàn Pé Ó Jẹ́ Kánjúkánjú. Alàgbà kan fọ̀rọ̀ wá ọ̀rọ̀ wò lẹ́nu àwọn akéde méjì tàbí mẹ́ta tí wọ́n ṣe gbogbo ohun tó yẹ láti ṣètò àkókó wọn kí wọ́n bàa lè ṣe púpọ̀ sí i lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù tàbí kí wọ́n lè ṣíṣẹ aṣáájú-ọ̀nà. Ní ìparí ọ̀rọ̀ rẹ, sọ ètò tí ìjọ ṣe fún jíjáde òde ẹ̀rí, kó o sì fún àwọn ará níṣìírí pé kí wọ́n ṣètò àwọn ìgbòkègbodò wọn kí wọ́n lè kópa ní kíkún lẹ́nu iṣẹ́ òjíṣẹ́.

10 min: Báwo Ni Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Ṣe Sunwọ̀n Sí? Ìjíròrò tí alábòójútó iṣẹ́ ìsìn máa bójú tó. Ní kí àwọn ará sọ bí àwọn àpilẹ̀kọ náà, “Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I” tá a jíròrò láwọn oṣù díẹ̀ sẹ́yìn ṣe mú kí wọ́n sunwọ̀n sí i ni onírúurú ọ̀nà lẹ́nu iṣẹ́ òjíṣẹ́ wọn. Ní ìparí, gba àwọn ará níyànjú pé kí wọ́n túbọ̀ máa kópa nínú iṣẹ́ ìwàásù lọ́nà tó fi hàn pé ó jẹ́ kánjúkánjú nípa fífi àwọn àbá tó wà nínú àwọn àpilẹ̀kọ náà sílò.

Orin 100 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́