Àwọn Ìfilọ̀
◼ Ìwé tá a máa lò ní January àti February: Ẹ lo èyíkéyìí lára àwọn ìwé pẹlẹbẹ olójú ewé méjìlélọ́gbọ̀n yìí: Ìròyìn Ayọ̀ Látọ̀dọ̀ Ọlọ́run!, Tẹ́tí sí Ọlọ́run tàbí Tẹ́tí sí Ọlọ́run Kó O Lè Wà Láàyè Títí Láé. March àti April: Ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ àti Jí!
◼ Bẹ̀rẹ̀ láti oṣù March 2015, àkòrí àsọyé fún gbogbo ènìyàn tí àwọn alábòójútó àyíká yóò máa sọ ni “Ìrísí Ìran Ayé Yìí Ń Yí Padà.”