Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ March 23
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ MARCH 23
Orin 119 àti Àdúrà
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
cl orí 22 ìpínrọ̀ 1 sí 8 (30 min.)
Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: 1 Sámúẹ́lì 10-13 (8 min.)
No. 1: 1 Sámúẹ́lì 11:1-10 (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
No. 2: Kí Ni Bíbélì Sọ Tẹ́lẹ̀ Nípa Ọjọ́ Wa?—igw ojú ìwé 12 ìpínrọ̀ 1 sí 4 (5 min.)
No. 3: Báwo La Ṣe Lè Fi Ìtọ́ni Tó Wà Nínú Mátíù 10:16 Sílò? (5 min.)
Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
ẸṢIN Ọ̀RỌ̀ OṢÙ YÌÍ: “Gbára Dì fún Iṣẹ́ Rere Gbogbo.”—Títù 3:1.
30 min: “Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn Pápá Tó Ń Gbéni Ró, Tó Ń Múni Gbára Dì, Tó sì Ń Mú Ká Wà Létòlétò.” Ìbéèrè àti ìdáhùn.
Orin 32 àti Àdúrà