Àwọn Ìfilọ̀
◼ Ìwé tá a máa lò ní April: Ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ àti Jí! May àti June: Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? tàbí Ṣé Wàá Fẹ́ Mọ Òtítọ́? July: Ẹ lo èyíkéyìí lára àwọn ìwé pẹlẹbẹ olójú ewé méjìlélọ́gbọ̀n yìí: Tẹ́tí sí Ọlọ́run, Tẹ́tí sí Ọlọ́run Kó O Lè Wà Láàyè Títí Láé, Ọ̀nà Tó Lọ sí Ìyè Àìnípẹ̀kun—Ṣé O Ti Rí I?, Kí Ní Ń Ṣẹlẹ̀ sí Wa Nígbà Tí A Bá Kú?, Ki Ni Ète Igbesi-Aye? àti Ìwọ́ Lè Di Ọ̀rẹ́ Ọlọ́run!
◼ Lọ́jọ́ Friday, May 29, 2015, kò ní sáyè fún wa láti gbàlejò ní Bẹ́tẹ́lì. Ẹ jọ̀wọ́, ẹ má ṣèbẹ̀wò, bẹ́ẹ̀ ni kẹ́ ẹ má ṣe wá gba ìwé lọ́jọ́ náà.