Ìtòlẹ́sẹẹsẹ fún Ọ̀sẹ̀ November 23
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ NOVEMBER 23
Orin 26 àti Àdúrà
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
ia orí 3 ìpínrọ̀ 1 sí 13, àti àpótí tó wà lójú ìwé 29 (30 min.)
Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: 2 Kíróníkà 1-5 (8 min.)
No. 1: 2 Kíróníkà 3:14–4:6 (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
No. 2: Ìfẹ́ Kì Í Jowú—1 Kọ́r. 13:4 (5 min.)
No. 3: Ṣé Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Ni Bíbélì Lóòótọ́? Báwo Ni Wọ́n Ṣe Kọ Ọ́?—wp14 2/1 ojú ìwé 16 ìpínrọ̀ 1 sí 4 (5 min.)
Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
Ẹṣin Ọ̀rọ̀ oṣù Yìí: “Èmi gbìn, Àpólò bomi rin, ṣùgbọ́n Ọlọ́run ń mú kí ó máa dàgbà.”—1 Kọ́r. 3:6.
10 min: “Ìmúrasílẹ̀ Tó Yẹ Ká Ṣe Ká Lè Kọ́ni Lọ́nà Tó Já Fáfá.” Àsọyé.
10 min: Ìwà Rere Tá A Bá Hù Máa fún Wa Láǹfààní Láti Fúnrúgbìn Òtítọ́. Ìjíròrò tó dá lórí Ìwé Ọdọọdún 2015, ojú ìwé 49, ìpínrọ̀ 3 sí ojú ìwé 51, ìpínrọ̀ 3 àti ojú ìwé 140, ìpínrọ̀ 3 sí ojú ìwé 141, ìpínrọ̀ 3. Ní kí àwọn ará sọ ẹ̀kọ́ tí wọ́n rí kọ́.
10 min: “Máa Lo Àwọn Ohun Pàtàkì Tó Wà Nínú Ìwé Bíbélì Fi Kọ́ni Lọ́nà Tó Gbéṣẹ́.” Ìjíròrò. Ṣe àṣefihàn ṣókí kan.
Orin 123 àti Àdúrà