Àwọn Ìfilọ̀
◼ Ìwé tá a máa lò ní December: Ẹ lo àwọn ìwé àṣàrò kúkúrú yìí: Irú Ìwé Wo Ni Bíbélì Jẹ́?, Kí Ló Lè Mú Kí Ìdílé Láyọ̀?, Kí Ló Máa Ṣẹlẹ̀ Lọ́jọ́ Ọ̀la?, Ǹjẹ́ Àwọn Òkú Lè Jíǹde?, Ǹjẹ́ Ìyà Lè Dópin?, Ṣé Wàá Fẹ́ Mọ Òtítọ́? àti Ta Ló Ń Darí Ayé Yìí? January àti February: Ìwọ Lè Di Ọ̀rẹ́ Ọlọ́run!, Ki Ni Ète Igbesi-Aye? Bawo Ni Iwọ Ṣe Le Rí I?, Kí Ní Ń Ṣẹlẹ̀ sí Wa Nígbà tí A Bá Kú?, Ọlọrun Ha Bikita Nipa Wa Niti Gidi Bi?, Ọ̀nà Tó Lọ sí Ìyè Àìnípẹ̀kun—Ṣé O Ti Rí I?, Tẹ́tí sí Ọlọ́run àti Tẹ́tí sí Ọlọ́run Kó O Lè Wà Láàyè Títí Láé. March: Ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ àti Jí!
◼ Ìrántí Ikú Kristi ti ọdún 2017 yóò wáyé ní Tuesday, April 11, 2017.