ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | NEHEMÁYÀ 1-4
Nehemáyà Fẹ́ràn Ìjọsìn Tòótọ́
Bíi Ti Orí Ìwé
455 B.C.E.
Nísàn (Mar. sí Apr.)
2:4-6 Nehemáyà gba àṣẹ láti tún Jerúsálẹ́mù tí wọ́n ti ń ṣe ìjọsìn tòótọ́ ní àkókò rẹ̀ kọ́
Ííyà
Sífánì
Támúsì (June sí July)
2:11-15 Nehemáyà dé Jerúsálẹ́mù nírú àkókò yìí, ó sì ṣàyẹ̀wò ògiri ìlú náà
Ábì (July sí Aug.)
Élúlì (Aug. sí Sept.)
6:15 Wọ́n parí mímọ ògiri náà lẹ́yìn ọjọ́ méjìléláàádọ́ta [52]
Tíṣírì