ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 March ojú ìwé 4
  • March 14 Sí 20

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • March 14 Sí 20
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 March ojú ìwé 4

March 14 Sí 20

JÓÒBÙ 1-5

  • Orin 89 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Jóòbù Pa Ìwà Títọ́ Rẹ̀ Mọ́ Nígbà Àdánwò”: (10 min.)

    • [Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tá a pe àkọlé rẹ̀ ní Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jóòbù.]

    • Job 1:8-11​—Sátánì jiyàn nípa ìdí tí Jóòbù fi pa ìwà títọ́ rẹ̀ mọ́ (w11 5/15 ojú ìwé 17 ìpínrọ̀ 6 sí 8; w09 4/15 ojú ìwé 3 ìpínrọ̀ 3 àti 4)

    • Job 2:2-5​—Sátánì sọ pé gbogbo èèyàn ò ní lè pa ìwà títọ́ wọn mọ́ (w09 4/15 ojú ìwé 4 ìpínrọ̀ 6)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Job 1:6; 2:1​—Àwọn wo ni Jèhófà gbà láyè kó wọlé wá láti dúró níwájú rẹ̀? (w06 3/15 ojú ìwé 13 ìpínrọ̀ 6)

    • Job 4:7, 18, 19​—Ọ̀rọ̀ tí kì í ṣe òótọ́ wo ni Élífásì sọ fún Jóòbù? (w14 3/15 ojú ìwé 13 ìpínrọ̀ 3; w05 9/15 ojú ìwé 26 ìpínrọ̀ 4-5; w95 2/15 ojú ìwé 27 ìpínrọ̀ 5-6)

    • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

    • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

  • Bíbélì Kíkà: Job 4:1-21 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: wp16.2 àwòrán iwájú ìwé​—Sọ ohun tí wàá bá ẹni náà jíròrò nígbà tó o bá pa dà wá. (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

  • Ìpadàbẹ̀wò: wp16.2 àwòrán iwájú ìwé​—Sọ ohun tí wàá bá ẹni náà jíròrò nígbà tó o bá tún pa dà wá. (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: fg ẹ̀kọ́ 2 ìpínrọ̀ 2 àti 3 (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 88

  • Má Ṣe Jẹ́ Kí Àwọn Ẹgbẹ́ Ẹ Ba Ìwà Ẹ Jẹ́!: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tá a pe àkọlé rẹ̀ ní Má Ṣe Jẹ́ Kí Àwọn Ẹgbẹ́ Ẹ Ba Ìwà Ẹ Jẹ́! ó wà lórí ìkànnì jw.org/yo (Lọ sí Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN Ọ̀DỌ́.) Lẹ́yìn náà, bi àwọn ará láwọn ìbéèrè yìí: Àwọn nǹkan wo làwọn ọmọ kan ń ṣe nílé ẹ̀kọ́ tí wọ́n á sì fẹ́ káwọn ọmọ míì máa bá wọn ṣe? Báwo làwọn ọmọ ṣe lè tẹ̀ lé ìlànà tó wà ní Ẹ́kísódù 23:2? Àwọn ohun mẹ́rin wo làwọn ọmọdé lè ṣe táá jẹ́ kí wọ́n lè hùwà ọgbọ́n tí wọ́n á sì pa ìwà títọ́ wọn mọ́? Ní kí àwọn ọ̀dọ́ sọ ìrírí tó gbádùn mọ́ni tí wọ́n ní.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: ia orí 11 ìpínrọ̀ 1 sí 11 (30 min.)

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 149 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́