March Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé March 2016 Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò March 7 Sí 13 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | Ẹ́SÍTÉRÌ 6-10 Ẹ́sítérì Kò Mọ Tara Rẹ̀ Nìkan, Ó Gbèjà Jèhófà Àtàwọn Èèyàn Rẹ̀ MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Bí O Ṣe Lè Kọ Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tó O Fẹ́ Lò Láti Fi Ìwé Ìròyìn Lọni MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ẹ Kí Àwọn Tá A Pè Káàbọ̀ March 14 Sí 20 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JÓÒBÙ 1-5 Jóòbù Pa Ìwà Títọ́ Rẹ̀ Mọ́ Nígbà Àdánwò March 21 Sí 27 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JÓÒBÙ 6-10 Jóòbù Ọkùnrin Olóòótọ́ Sọ Ẹ̀dùn Ọkàn Rẹ̀ March 28 Sí April 3 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JÓÒBÙ 11-15 Jóòbù Gbà Pé Àjíǹde Máa Wà MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ìràpadà Mú Kí Àjíǹde Ṣeé Ṣe