ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 March ojú ìwé 5
  • March 21 Sí 27

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • March 21 Sí 27
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 March ojú ìwé 5

March 21 Sí 27

JÓÒBÙ 6-10

  • Orin 68 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Jóòbù Ọkùnrin Olóòótọ́ Sọ Ẹ̀dùn Ọkàn Rẹ̀”: (10 min.)

    • Job 6:1-3, 9, 10, 26; 7:11, 16​—Tí ìdààmú bá bá àwọn èèyàn, kì í ṣe ohun tí wọ́n ní lọ́kàn gan-an ni wọ́n sábà máa ń sọ (w13 8/15 19 ¶7; w13 5/15 22 ¶13)

    • Job 9:20-22​—Àwọn ìṣòro tí Jóòbù ní mú kó ní èrò tí kò tọ́, ó rò pé ojú kan náà ni Ọlọ́run fi ń wo ẹni burúkú àti ẹni rere (w15 ojú ìwé 12 ìpínrọ̀ 2)

    • Job 10:12​—Kódà nígbà tí Jóòbù kojú àdánwò tó lè koko, ó sọ àwọn ohun tó dára nípa Jèhófà (w09 4/15 7 ¶18; w09 4/15 10 ¶13)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Job 6:14​—Báwo ni Jóòbù ṣe fi hàn pé ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ ṣe pàtàkì? (w10 11/15 ojú ìwé 32 ìpínrọ̀ 20)

    • Job 7:9, 10; 10:21​—Tí Jóòbù bá gbà pé àjíǹde wà, kí nìdí tó fi sọ ọ̀rọ̀ tó wà nínú ẹsẹ yìí? (w06 3/15 ojú ìwé 14 ìpínrọ̀ 11)

    • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

    • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

  • Bíbélì Kíkà: Job 9:1-21 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: wp16.2 ojú ìwé 16​—Sọ bí a ṣe ń fi ọrẹ ṣètìlẹyìn fún iṣẹ́ wa. (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

  • Ìpadàbẹ̀wò: wp16.2 ojú ìwé 16​—Sọ ohun tí wàá bá ẹni náà jíròrò nígbà tó o bá tún pa dà wá. (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: fg ẹ̀kọ́ 2 ìpínrọ̀ 6 sí 8 (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 114

  • Máa Lo Ìjìnlẹ̀ Òye Tó O Bá Ń Tu Àwọn Èèyàn Nínú: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tí àwọn alàgbà wò láìpẹ́ yìí ní Ilé Ẹ̀kọ́ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́. Lẹ́yìn náà, ní kí àwọn ará sọ bí àwọn arákùnrin méjì tá a rí nínú fídíò náà ṣe fi àpẹẹrẹ rere lélẹ̀ fún wa nípa bí a ṣe lè tu ẹni tó sọ ẹ̀dùn ọkàn rẹ̀ fún wa nínú lẹ́yìn tí èèyàn rẹ̀ kan kú.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: ia orí 11 ìpínrọ̀ 12 sí 20, àtúnyẹ̀wò tó wà lójú ìwé 98 (30 min.)

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 27 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́