ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 March ojú ìwé 5
  • Jóòbù Ọkùnrin Olóòótọ́ Sọ Ẹ̀dùn Ọkàn Rẹ̀

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jóòbù Ọkùnrin Olóòótọ́ Sọ Ẹ̀dùn Ọkàn Rẹ̀
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Jobu Lo Ìfaradà—Àwa Pẹ̀lú Lè Ṣe Bẹ́ẹ̀!
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1994
  • Jóòbù Gbé Orúkọ Jèhófà Ga
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2009
  • “Mi Ò Ní Fi Ìwà Títọ́ Mi Sílẹ̀!”
    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn
  • Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Jóòbù
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2006
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 March ojú ìwé 5

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JÓÒBÙ 6-10

Jóòbù Ọkùnrin Olóòótọ́ Sọ Ẹ̀dùn Ọkàn Rẹ̀

Àwọn ọ̀rẹ́ Jóòbù mẹ́ta

Jóòbù ò ní dúkìá kankan mọ́, ó ti pàdánù àwọn ọmọ rẹ̀, àìsàn burúkú kan ń ṣe é, síbẹ̀ ó ṣì jẹ́ olóòótọ́. Sátánì gbìyànjú láti mú kí Jóòbù rẹ̀wẹ̀sì kó lè ba ìṣòtítọ́ rẹ̀ jẹ́. Àwọn “ọ̀rẹ́” rẹ̀ mẹ́ta dé. Wọ́n kọ́kọ́ ṣe bí ẹni pé wọ́n fẹ́ bá a kẹ́dùn. Wọ́n wá jókòó ti Jóòbù fún ọjọ́ méje láì sọ̀rọ̀ ìtùnú kankan fún un. Ìgbà tí wọ́n tún máa sọ̀rọ̀, ńṣe ni wọ́n fi ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀sùn kàn án.

Jóòbù pa ìwà títọ́ rẹ̀ sí Jèhófà mọ́ láì ka ìdààmú tó bá a sí

6:3; 7:16; 9:20-22; 10:1, 12

  • Ìbànújẹ́ tó lágbára tó bá Jóòbù mú kó ronú lọ́nà tí kò tọ́. Èrò tí kò tọ́ tó ní yìí mú kó ronú pé ìwà títọ́ òun kò já mọ́ nǹkan kan lójú Ọlọ́run

  • Torí ìrẹ̀wẹ̀sì tó dé bá Jóòbù, kò ronú lórí ohun tó ṣeé ṣe kó fa ìyà tó ń jẹ ẹ́

  • Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ìbànújẹ́ dorí Jóòbù kodò, ó ṣì sọ̀rọ̀ nípa bó ṣe nífẹ̀ẹ́ Jèhófà tó fáwọn tó fẹ̀sùn kàn án

Eéwo wà ní gbogbo ara Jóòbù
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́