ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 March ojú ìwé 6
  • March 28 Sí April 3

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • March 28 Sí April 3
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 March ojú ìwé 6

March 28 Sí April 3

JÓÒBÙ 11-15

  • Orin 111 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Jóòbù Gbà Pé Àjíǹde Máa Wà”: (10 min.)

    • Job 14:1, 2​—Jóòbù ṣe àkópọ̀ bí ìgbésí ayé àwa èèyàn ṣe rí (w15 3/1 ojú ìwé 3; w10 5/1 ojú ìwé 5 ìpínrọ̀ 2; w08 3/1 ojú ìwé 3 ìpínrọ̀ 3)

    • Job 14:13-15a​—Jóòbù mọ̀ pé Jèhófà kò ní gbàgbé òun (w15 8/1 ojú ìwé 5; w14 1/1 ojú ìwé 7 ìpínrọ̀ 4; w11 3/1 ojú ìwé 22 ìpínrọ̀ 2 sí 4)

    • Job 14:15b​—Jèhófà mọyì àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ olóòótọ́ (w15 8/1 ojú ìwé 7 ìpínrọ̀ 3; w14 6/15 ojú ìwé 14 ìpínrọ̀ 12; w11 3/1 ojú ìwé 22 ìpínrọ̀ 3 sí 6)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Job 12:12​—Kí nìdí tí àwọn Kristẹni tó jẹ́ àgbàlagbà fi lè ran àwọn ọ̀dọ́ lọ́wọ́? (g99 8/8 ojú ìwé 19, àpótí)

    • Job 15:27​—Kí ni Élífásì ní lọ́kàn nígbà tó dọ́gbọ́n sọ fún Jóòbù pé ‘ọ̀rá ni ó fi bo ojú ara rẹ̀’? (it-1 ojú ìwé 802 ìpínrọ̀ 4)

    • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

    • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

  • Bíbélì Kíkà: Job 14:1-22 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: fg ẹ̀kọ́ 13 ìpínrọ̀ 1​—Sọ ohun tí wàá bá ẹni náà jíròrò nígbà tó o bá pa dà wá. (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

  • Ìpadàbẹ̀wò:: fg ẹ̀kọ́ 13 ìpínrọ̀ 2​—Sọ ohun tí wàá bá ẹni náà jíròrò nígbà tó o bá tún pa dà wá. (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: fg ẹ̀kọ́ 13 ìpínrọ̀ 3 àti 4 (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀))

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 134

  • Ohun tó ń fẹ́ àbójútó nínú ìjọ: (5 min.)

  • “Ìràpadà Mú Kí Àjíǹde Ṣeé Ṣe”: (10 min.) Ìjíròrò. Ní ìparí ìjíròrò yìí, jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tá a wò ní Àpéjọ Àgbègbè “Ẹ Kọ́kọ́ Máa Wá Ìjọba Ọlọ́run!” ti ọdún 2014.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: ia orí 12 ìpínrọ̀ 1 sí 12 (30 min.)

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 33 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́