ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 April ojú ìwé 4
  • April 11 Sí 17

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • April 11 Sí 17
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 April ojú ìwé 4

April 11 Sí 17

JÓÒBÙ 21-27

  • Orin 83 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Jóòbù Kò Fàyè Gba Èrò Òdì”: (10 min.)

    • Job 22:2-7​—Élífásì dá lórí èrò èké àti èrò tara rẹ̀ (w06 3/15 ojú ìwé 15 ìpínrọ̀ 7; w05 9/15 ojú ìwé 26 àti 27; w95 2/15 ojú ìwé 27 ìpínrọ̀ 6)

    • Job 25:4, 5​—Ọ̀rọ̀ tí kì í ṣe òótọ́ ni Bílídádì sọ (w05 9/15 ojú ìwé 26 àti 27)

    • Job 27:5, 6​—Jóòbù kò jẹ́ kí àwọn èèyàn mú kó máa rò pé òun ò pa ìwà títọ́ òun mọ́ (w09 8/15 ojú ìwé 4 ìpínrọ̀ 8; w06 3/15 ojú ìwé 15 ìpínrọ̀ 9)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Job 24:2​—Kí nìdí tí sísún ààlà sẹ́yìn fí jẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ tó burú jáì (it-1-E ojú ìwé 360)

    • Job 26:7​—Kí nìdí tí ohun tí Jóòbù sọ nípa ayé fi ṣe pàtàkì? (w15 6/1 ojú ìwé 5 ìpínrọ̀ 4; w11 7/1 ojú ìwé 26 ìpínrọ̀ 2 sí 5)

    • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

    • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

  • Bíbélì Kíkà: Job 27:1-23 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: Àwòrán iwájú ìwé ìròyìn g16.2​—Sọ ohun tí wàá bá ẹni náà jíròrò nígbà tó o bá pa dà wá. (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

  • Ìpadàbẹ̀wò: Àwòrán iwájú ìwé ìròyìn g16.2​—Sọ ohun tí wàá bá ẹni náà jíròrò nígbà tó o bá tún pa dà wá. (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: bh ojú ìwé 145 ìpínrọ̀ 3 àti 4 (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 129

  • Bó O Ṣe Lè Borí Ẹni Tó Ń Halẹ̀ Mọ́ Ẹ Láì Bá A Jà: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò eré ojú pátákó tá a pe àkọlé rẹ̀ ní Bó O Ṣe Lè Borí Ẹni Tó Ń Halẹ̀ Mọ́ Ẹ Láì Bá A Jà. (Lọ sí jw.org/yo, kó o sì wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN Ọ̀DỌ́.) Lẹ́yìn náà, ẹ jíròrò àwọn ìbéèrè yìí: Kí nìdí tí wọ́n fi lè máa halẹ̀ mọ́ ẹnì kan? Ìpalára wo ni híhalẹ̀ mọ́ni máa ń fà? Báwo lo ṣe lè borí ẹni tó ń halẹ̀ mọ́ ẹ tàbí kó o yẹra fún un? Ta lo lè sọ fún tí wọ́n bá ń halẹ̀ mọ́ ẹ? Tọ́ka sí orí 14 ìwé Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè, Apá 2.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: ia orí 13 ìpínrọ̀ 1 sí 12 (30 min..)

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 23 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́