April Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé April 2016 Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò April 4 Sí 10 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JÓÒBÙ 16-20 Máa Sọ Ọ̀rọ̀ Rere Tó Ń Gbéni Ró Tó sì Ń Fúnni Lókun MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ohun Tuntun Tá A Lè Fi Bẹ̀rẹ̀ Ìjíròrò April 11 Sí 17 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JÓÒBÙ 21-27 Jóòbù Kò Fàyè Gba Èrò Òdì April 18 Sí 24 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JÓÒBÙ 28-32 Jóòbù Fi Àpẹẹrẹ Ìwà Títọ́ Lélẹ̀ April 25 Sí May 1 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JÓÒBÙ 33-37 Ọ̀rẹ́ Tòótọ́ Máa Ń Sọ Ọ̀rọ̀ Tó Gbéni Ró MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ A Máa Pín Ìwé Ìkésíni sí Àpéjọ Àgbègbè MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Àwọn Ohun Tó Yẹ Ká Fi Sọ́kàn Nípa Àpéjọ Àgbègbè