ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 April ojú ìwé 5
  • Jóòbù Fi Àpẹẹrẹ Ìwà Títọ́ Lélẹ̀

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jóòbù Fi Àpẹẹrẹ Ìwà Títọ́ Lélẹ̀
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Mi Ò Ní Fi Ìwà Títọ́ Mi Sílẹ̀!”
    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn
  • Jóòbù Gbé Orúkọ Jèhófà Ga
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2009
  • Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Jóòbù
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2006
  • Àwa Yóò Máa Rìn Nínú Ìwà Títọ́ wa!
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2010
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 April ojú ìwé 5

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JÓÒBÙ 28-32

Jóòbù Fi Àpẹẹrẹ Ìwà Títọ́ Lélẹ̀

Jóòbù pinnu láti máa tẹ̀ lé àwọn ìlànà Jèhófà nípa bó ṣe yẹ kéèyàn máa hùwà

31:1

  • Ó darí ojú rẹ̀ bó ṣe yẹ, ìyàwó rẹ̀ nìkan sì ni ọkàn rẹ̀ máa ń fà sí

    Jóòbù àti ìyàwó rẹ̀

Jóòbù fi àpẹẹrẹ rere lélẹ̀ nínú bó ṣe bá àwọn èèyàn lò

31:13-15

  • Ó jẹ́ onírẹ̀lẹ̀, kì í ṣe ojúsàájú, ó sì láàánú. Ó máa ń gba tàwọn èèyàn rò láìka ipò wọn sí àti bóyá wọ́n rí ṣe tàbí wọn ò rí ṣe

    Jóòbù àti ọ̀dọ́kùnrin kan jọ ń rìn

Jóòbù lawọ́, kì í ṣe onímọtara-ẹni-nìkan

31:16-19

  • Ó máa ń ran àwọn èèyàn lọ́wọ́, ó sì máa ń ṣoore fáwọn aláìní

    Jóòbù ń fún ọmọ kékeré kan ní èso àjàrà
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́