ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 May ojú ìwé 7
  • May 30 Sí June 5

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • May 30 Sí June 5
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 May ojú ìwé 7

May 30 Sí June 5

SÁÀMÙ 26-33

  • Orin 23 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Bẹ Jèhófà Pé Kó Jẹ́ Kó O Ní Ìgboyà”: (10 min.)

    • Sm 27:1-3—A máa ní ìgboyà tí a bá ń ronú lórí ọ̀nà tí Jèhófà gbà jẹ́ ìmọ́lẹ̀ wa (w12 7/15 ojú ìwé 22 àti 23 ìpínrọ̀ 3 sí 6)

    • Sm 27:4—Ìmọrírì tá a ní fún ìjọsìn tòótọ́ á máa fún wa lókun (w12 7/15 ojú ìwé 24 ìpínrọ̀ 7)

    • Sm 27:10—Jèhófà ṣe tán láti ti àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ lẹ́yìn nígbà táwọn èèyàn míì bá kọ̀ wọ́n sílẹ̀ (w12 7/15 ojú ìwé 24 ìpínrọ̀ 9 àti 10)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Sm 26:6—Bíi ti Dáfídì, báwo la ṣe ń rìn yí ká pẹpẹ Jèhófà lọ́nà ìṣàpẹẹrẹ? (w06 5/15 ojú ìwé 19 ìpínrọ̀ 11)

    • Sm 32:8—Àǹfààní wo la máa rí tí Jèhófà bá fún wa ní ìjìnlẹ̀ òye? (w09 6/1 ojú ìwé 5 ìpínrọ̀ 3)

    • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

    • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sáàmù 32:1–33:8

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) kt—Ka ẹsẹ Ìwé Mímọ́ kan fún onílé lórí fóònù tàbí tablet rẹ.

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Fi fídíò náà Báwo La Ṣe Máa Ń Ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? tó wà lórí JW Library rẹ ṣe àṣefihàn bí o ṣe lè bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì pẹ̀lú ẹnì kan tó o máa ń fún ní ìwé ìròyìn déédéé. Jẹ́ kí ẹni náà wo fídíò yìí.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) jl ẹ̀kọ́ 9—Ní ṣókí, fi han ẹni tí ò ń kọ́ lẹ́kọ̀ọ́ bó ṣe lè fi JW Library múra ìpàdé sílẹ̀.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 130

  • Ohun tó ń fẹ́ àbójútó nínú ìjọ: (15 min.) Ní àfidípò, ẹ jíròrò ẹ̀kọ́ tí a rí kọ́ nínú Ìwé Ọdọọdún. (yb16 ojú ìwé 112 sí 113 àti ojú ìwé 135 sí 136)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) ia orí 16 ìpínrọ̀ 16 sí 29 àti àpótí tó wà lójú ìwé 142, àtúnyẹ̀wò tó wà lójú ìwé 144

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 16 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́