May Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé May 2016 Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò May 2 Sí 8 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JÓÒBÙ 38-42 Inú Jèhófà Máa Ń Dùn Tá A Bá Gbàdúrà Fáwọn Ẹlòmíì MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ǹjẹ́ Ò Ń Lo Ètò Ìṣiṣẹ́ JW Library? May 9 Sí 15 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | SÁÀMÙ 1-10 Tá A Bá Fẹ́ Wà Ní Àlááfíà Pẹ̀lú Jèhófà, A Ní Láti Bọ̀wọ̀ fún Jésù Ọmọ Rẹ̀ May 16 Sí 22 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | SÁÀMÙ 11-18 Ta Ló Lè Jẹ́ Àlejò Nínú Àgọ́ Jèhófà? MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Àwọn Ọ̀nà Tó O Lè Gbà Lo Ètò Ìṣiṣẹ́ JW Library May 23 Sí 29 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | SÁÀMÙ 19-25 Àwọn Àsọtẹ́lẹ̀ Jẹ́ Ká Mọ Púpọ̀ Sí I Nípa Mèsáyà May 30 Sí June 5 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | SÁÀMÙ 26-33 Bẹ Jèhófà Pé Kó Jẹ́ Kó O Ní Ìgboyà