ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 May ojú ìwé 5
  • May 16 Sí 22

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • May 16 Sí 22
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 May ojú ìwé 5

May 16 Sí 22

SÁÀMÙ 11-18

  • Orin 106 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ta Ló Lè Jẹ́ Àlejò Nínú Àgọ́ Jèhófà?”: (10 min.)

    • Sm 15:1, 2—A gbọ́dọ̀ máa sọ òtítọ́ nínú ọkàn wa (w03 8/1 ojú ìwé 14 ìpínrọ̀ 18; w89 9/15 ojú ìwé 26 ìpínrọ̀ 7)

    • Sm 15:3—Ó yẹ ká máa sọ̀rọ̀ tó ń gbéni ró (w89 10/15 ojú ìwé 12 ìpínrọ̀ 10 àti 11; w89 9/15 ojú ìwé 27 ìpínrọ̀ 2 àti 3; it-2-E ojú ìwé 779)

    • Sm 15:4, 5—A gbọ́dọ̀ jẹ́ olóòótọ́ nínú gbogbo ohun tá a bá ń ṣe (w06 5/15 ojú ìwé 19 ìpínrọ̀ 2; w89 9/15 ojú ìwé 29 àti 30; it-1-E ojú ìwé 1211 ìpínrọ̀ 3)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Sm 11:3—Kí ni ìtumọ̀ ẹsẹ Bíbélì yìí? (w06 5/15 ojú ìwé 18 ìpínrọ̀ 3; w05 5/15 ojú ìwé 32 ìpínrọ̀ 2)

    • Sm 16:10—Báwo ni àsọtẹ́lẹ̀ tó wà ní Sáàmù 16:10 ṣe ṣẹ sí Jésù Kristi lára? (w11 8/15 ojú ìwé 16 ìpínrọ̀ 19; w05 5/1 ojú ìwé 14 ìpínrọ̀ 9)

    • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

    • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sáàmù 18:1-19

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) wp16.3 ojú ìwé 16—Ka ẹsẹ Ìwé Mímọ́ kan fún onílé lórí fóònú tàbí tablet rẹ.

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) wp16.3 ojú ìwé 16—Ka ẹsẹ Ìwé Mímọ́ kan fún onílé ní èdè rẹ̀ lórí JW Library.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh ojú ìwé 100 sí 101 ìpínrọ̀ 10 àti 11​—Ní ṣókí, fi han ẹni tí ò ń kọ́ lẹ́kọ̀ọ́ bó ṣe lè fi JW Library ṣe ìwádìí ìdáhùn ìbéèrè tó béèrè lọ́wọ́ rẹ.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 70

  • “Àwọn Ọ̀nà Tó O Lè Gbà Lo Ètò Ìṣiṣẹ́ JW Library”—Apá Kìíní: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo àwọn fídíò tá a pè ní Máa Lo Ohun Tó O Lè Fi Ṣàmì Sórí Ìtẹ̀jáde—Bookmarks àti Máa Lo Ohun Tó O Lè Fi Pa Dà Síbi Tó O Kà Tẹ́lẹ̀—History, kó o sì jíròrò wọn ní ṣókí. Lẹ́yìn náà, jíròrò àwọn ìsọ̀rí méjì àkọ́kọ́ nínú àpilẹ̀kọ náà. Ní kí àwọn ará sọ àwọn ọ̀nà míì tí wọ́n ti gbà lo ètò ìṣiṣẹ́ JW Library nígbà ìdákẹ́kọ̀ọ́ àti ní ìpàdé.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) ia orí 15 ìpínrọ̀ 15 sí 26 àti àtúnyẹ̀wò tó wà lójú ìwé 134

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 43 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́