ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 June ojú ìwé 2
  • June 6 Sí 12

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • June 6 Sí 12
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 June ojú ìwé 2

June 6 Sí 12

SÁÀMÙ 34-37

  • Orin 95 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà, Kí O sì Máa Ṣe Rere”: (10 min.)

    • Sm 37:1, 2​—Pọkàn pọ̀ sórí bó o ṣe ń sin Jèhófà, má ṣe wo àṣeyọrí àwọn aṣebi tí kì í tọ́jọ́ (w03 12/1 ojú ìwé 9 àti 10 ìpínrọ̀ 3 sí 6)

    • Sm 37:3-6​—Gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà, máa ṣe rere, kó o sì gba ìbùkún (w03 12/1 ojú ìwé 10 sí 12 ìpínrọ̀ 7 sí 15)

    • Sm 37:7-11​—Fi sùúrù dúró de Jèhófà láti mú àwọn ẹni burúkú kúrò (w03 12/1 ojú ìwé 13 ìpínrọ̀ 16 sí 20)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Sm 34:18​—Báwo ni Jèhófà ṣe máa ń bójú tó àwọn “oníròbìnújẹ́ ní ọkàn-àyà” àti “àwọn tí a wó ẹ̀mí wọn palẹ̀”? (w11 6/1 ojú ìwé 19)

    • Sm 34:20​—Báwo ni àsọtẹ́lẹ̀ yìí ṣe ṣẹ sí Jésù lára? (w13 12/15 ojú ìwé 21 ìpínrọ̀ 19)

    • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

    • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sm 35:19–36:12

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Múra Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Oṣù Yìí Sílẹ̀: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn fídíò ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀, kó o sì jíròrò àwọn kókó pàtàkì látinú àwọn fídíò náà. Gba àwọn ará níyànjú pé kí wọ́n kọ àwọn ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ wọn sílẹ̀.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 93

  • “Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I​—⁠Bí O Ṣe Lè Fi Fídíò Kọ́ni Lẹ́kọ̀ọ́”: (15 min.) Ìjíròrò. Fi fídíò tó wà lórí ìkànnì jw.org/⁠yo tá a pe àkọlé rẹ̀ ní Ta Ni Òǹṣèwé Bíbélì? ṣàlàyé àwọn kókó tó wà lábẹ́ ìsọ̀rí náà “Bó O Ṣe Lè Ṣe É.” (Wo abẹ́ ÀWỌN ÌTẸ̀JÁDE > ÀWỌN ÌWÉ ŃLA ÀTÀWỌN ÌWÉ PẸLẸBẸ. Lẹ́yìn náà, lọ síbi tí ìwé Ìròyìn Ayọ̀ wà, kó o sì ṣí i. Wàá rí fídíò náà lábẹ́ ẹ̀kọ́ tá a pe àkòrí rẹ̀ ní “Ṣé Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Ni Ìròyìn Ayọ̀ Ti Wá Lóòótọ́?”)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) ia orí 17 ìpínrọ̀ 1 sí 13

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 61 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́