ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 June ojú ìwé 4
  • June 13 Sí 19

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • June 13 Sí 19
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 June ojú ìwé 4

June 13 Sí 19

SÁÀMÙ 38-44

  • Orin 4 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Jèhófà Máa Ń Gbé Àwọn Aláìsàn Ró”: (10 min.)

    • Sm 41:​1, 2​—⁠Aláyọ̀ ni àwọn tó ń fi ìgbatẹnirò hàn sí àwọn ẹni rírẹlẹ̀ (w15 12/⁠15 ojú ìwé 24 ìpínrọ̀ 7; w91 10/⁠1 ojú ìwé 14 ìpínrọ̀ 6)

    • Sm 41:3​—⁠Jèhófà bìkítà fún àwọn olódodo tó ń ṣàìsàn (w08 9/⁠15 ojú ìwé 5 ìpínrọ̀ 12 àti 13)

    • Sm 41:12​—⁠Ìrètí ọjọ́ iwájú máa jẹ́ kí ẹni tó ń ṣàìsàn fara dà á (w15 12/⁠15 ojú ìwé 27 ìpínrọ̀ 18 àti 19; w08 12/⁠15 ojú ìwé 6 ìpínrọ̀ 15)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Sm 39:​1, 2​—⁠Kí nìdí tó fi yẹ ká kíyè sí ohun tá a máa sọ? (w09 5/⁠15 ojú ìwé 4 ìpínrọ̀ 5; w06 5/⁠15 ojú ìwé 20 ìpínrọ̀ 12)

    • Sm 41:9​—Báwo ni Jésù ṣe jẹ́ ká mọ̀ pé irú ohun tó ṣẹlẹ̀ sí Dáfídì ló ṣẹlẹ̀ sí òun náà? (w11 8/⁠15 ojú ìwé 13 ìpínrọ̀ 5; w08 9/⁠15 ojú ìwé 5 ìpínrọ̀ 11)

    • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

    • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sm 42:6–43:5

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Kókó iwájú ìwé ìròyìn g16.3

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Àpilẹ̀kọ tó dá lórí kókó iwájú ìwé ìròyìn g16.3

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg ẹ̀kọ́ 2 ìpínrọ̀ 4 àti 5​—⁠Ní ìparí ìkẹ́kọ̀ọ́, jẹ́ kí akẹ́kọ̀ọ́ rẹ wo fídíò tó wà lórí ìkànnì jw.org/⁠yo tá a pè ní Ṣé Ọlọ́run ní Orúkọ?

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 128

  • Tẹjú Mọ́ Èrè Náà!: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò tó wà lórí ìkànnì jw.org/⁠yo tá a pè ní Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà​—⁠Tẹjú Mọ́ Èrè Náà! (Orin 24). (Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN ỌMỌDÉ.) Lẹ́yìn náà, jíròrò eré tá a pe àkọlé rẹ̀ ní “Fi Wọ́n Wéra: Ayé Ìsinsìnyí àti Ọjọ́ Iwájú.” Béèrè àwọn ìbéèrè yìí: Àwọn ìyípadà wo ló máa wáyé ní Párádísè? Àwọn ìbùkún wo lò ń fojú sọ́nà fún? Báwo ni ríronú lórí àwọn ohun rere tó ń bọ̀ ṣe lè jẹ́ kó o máa lo ìfaradà?​—2Kọ 4:18.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) ia orí 17 ìpínrọ̀ 14 sí 22 àti àtúnyẹ̀wò tó wà lójú ìwé 152

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 36 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́