ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 June ojú ìwé 6
  • June 27 Sí July 3

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • June 27 Sí July 3
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 June ojú ìwé 6

June 27 Sí July 3

SÁÀMÙ 52-59

  • Orin 38 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ju Ẹrù Ìnira Rẹ Sọ́dọ̀ Jèhófà”: (10 min.)

    • Sm 55:2, 4, 5, 16-18​—Àwọn ìgbà kan wà tí ìdààmú ọkàn bá Dáfídì gan-an (w06 6/⁠1 ojú ìwé 11 ìpínrọ̀ 3; w96 4/⁠1 ojú ìwé 27 ìpínrọ̀ 2)

    • Sm 55:​12-14​—Ọmọ Dáfídì àti ọ̀rẹ́ Dáfídì kan tó fọkàn tán dìtẹ̀ mọ́ ọn (w96 4/⁠1 ojú ìwé 30 ìpínrọ̀ 1)

    • Sm 55:22​—Ó dá Dáfídì lójú pé Jèhófà máa ràn òun lọ́wọ́ (w06 6/⁠1 ojú ìwé 11 ìpínrọ̀ 4; w99 3/⁠15 ojú ìwé 22 sí 23)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Sm 56:8​—⁠Kí ni ọ̀rọ̀ náà “fi omijé mi sínú ìgò awọ rẹ” túmọ̀ sí? (w09 6/⁠1 ojú ìwé 29 ìpínrọ̀ 1; w08 10/⁠1 ojú ìwé 26 ìpínrọ̀ 3)

    • Sm 59:​1, 2​—⁠Kí ni ohun tó ṣẹlẹ̀ sí Dáfídì kọ́ wa nípa àdúrà? (w08 3/⁠15 ojú ìwé 14 ìpínrọ̀ 13)

    • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

    • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sm 52:1–53:6

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Fi ọ̀kan lára àwọn ìwé àṣàrò kúkúrú lọni. Fi àmì ìlujá tó wà lẹ́yìn rẹ̀ han onílé.

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ṣe àṣefihàn bí a ṣe lè ṣe ìpadàbẹ̀wò ẹni tó gba ìwé àṣàrò kúkúrú.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) fg ẹ̀kọ́ 3 ìpínrọ̀ 2 àti 3​—⁠Ní ìparí ìkẹ́kọ̀ọ́, jẹ́ kí akẹ́kọ̀ọ́ rẹ wo fídíò tó wà lórí ìkànnì jw.org/⁠yo tá a pè ní Báwo La Ṣe Mọ̀ Pé Òótọ́ ni Ọ̀rọ̀ Inú Bíbélì?

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 56

  • Ohun tó ń fẹ́ àbójútó nínú ìjọ: (7 min.)

  • “Ọlọ́run Ni Olùrànlọ́wọ́ Mi”: (8 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará dáhùn àwọn ìbéèrè tó wà nísàlẹ̀ yìí bó bá ti lè ṣeé ṣe tó, èyí á mú kí gbogbo wa lè jàǹfààní látinú ìrírí àwọn arákùnrin àtàwọn arábìnrin wa. (Ro 1:12) Gba àwọn ará níyànjú láti máa lo Ìwé Ìwádìí láti fi wá ohun tí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run sọ nígbà tí wọ́n bá níṣòro.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) ia orí 18 ìpínrọ̀ 14 sí 21 àti àtúnyẹ̀wò tó wà lójú ìwé 161

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 121 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́