ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 August ojú ìwé 2
  • August 1 Sí 7

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • August 1 Sí 7
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 August ojú ìwé 2

August 1 Sí 7

SÁÀMÙ 87-91

  • Orin 49 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Má Ṣe Kúrò Ní Ibi Ìkọ̀kọ̀ Ẹni Gíga Jù Lọ”: (10 min.)

    • Sm 91:​1, 2​—“Ibi ìkọ̀kọ̀” Jèhófà ń pèsè ààbò fún wa nípa tẹ̀mí (w10 2/⁠15 ojú ìwé 26 àti 27 ìpínrọ̀ 10 àti 11)

    • Sm 91:3​—Bíi ti pẹyẹpẹyẹ, Sátánì fẹ́ dẹ pańpẹ́ mú wa (w07 10/⁠1 ojú ìwé 26 sí 30 ìpínrọ̀ 1 sí 18)

    • Sm 91:​9-14​—Jèhófà ni ààbò wa (w10 1/⁠15 ojú ìwé 10 àti 11 ìpínrọ̀ 13 àti 14; w01 11/⁠15 ojú ìwé 19 àti 20 ìpínrọ̀ 13 sí 19)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Sm 89:​34-37​—Májẹ̀mú wo ni àwọn ẹsẹ Bíbélì yìí ń tọ́ka sí, báwo sì ni Jèhófà ṣe ṣàpẹẹrẹ bó ṣe jóòótọ́ tó? (w14 10/⁠15 ojú ìwé 10 ìpínrọ̀ 14; w07 7/⁠15 ojú ìwé 32 ìpínrọ̀ 3 àti 4)

    • Sm 90:​10, 12​—Báwo ni a ṣe ń ‘ka àwọn ọjọ́ wa lọ́nà tí a ó fi ní ọkàn-àyà ọgbọ́n’? (w06 7/15 ojú ìwé 13 ìpínrọ̀ 4; w01 11/15 ojú ìwé 13 ìpínrọ̀ 19)

    • Ẹ̀kọ́ wo ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ mi nípa Jèhófà?

    • Àwọn kókó wo látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí ni mo lè lò lóde ẹ̀rí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Sm 90:​1-17

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Múra Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Oṣù Yìí Sílẹ̀: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn fídíò ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀, kó o sì jíròrò àwọn kókó pàtàkì látinú àwọn fídíò náà. Gba àwọn ará níyànjú pé kí wọ́n kọ àwọn ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ wọn sílẹ̀.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 141

  • Ohun tó ń fẹ́ àbójútó nínú ìjọ: (5 min.)

  • “Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I​—Ran Àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Rẹ Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Ṣe Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi”: (10 min.) Ìjíròrò. Lo àwọn ìbéèrè yìí láti fọ̀rọ̀ wá ọ̀rọ̀ wò lẹ́nu akéde kan tó ti ran ẹnì kan lọ́wọ́ débi pé onítọ̀hún ya ara rẹ̀ sí mímọ́, ó sì ṣèrìbọmi. Báwo lẹ ṣe ran akẹ́kọ̀ọ́ yín lọ́wọ́ kó lè nífẹ̀ẹ́ Jèhófà? Báwo lẹ ṣe ran akẹ́kọ̀ọ́ yín lọ́wọ́ kí ọwọ́ rẹ̀ lè tẹ àwọn àfojúsùn tẹ̀mí?

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) ia orí 21 ìpínrọ̀ 1 sí 12

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 137 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́