August Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni—Ìwé Ìpàdé August 2016 Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò August 1 Sí 7 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | SÁÀMÙ 87-91 Má Ṣe Kúrò Ní Ibi Ìkọ̀kọ̀ Ẹni Gíga Jù Lọ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Mú Kí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ Sunwọ̀n Sí I—Ran Àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Rẹ Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Ṣe Ìyàsímímọ́ àti Ìrìbọmi August 8 Sí 14 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | SÁÀMÙ 92-101 Bí Àwọn Àgbàlagbà Ṣe Lè Máa Sin Jèhófà Nìṣó August 15 Sí 21 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | SÁÀMÙ 102-105 Jèhófà Máa Ń Rántí Pé Ekuru Ni Wá August 22 Sí 28 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | SÁÀMÙ 106-109 “Ẹ Fi Ọpẹ́ Fún Jèhófà” August 29 Sí September 4 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | SÁÀMÙ 110-118 “Kí Ni Èmi Yóò San Pa Dà Fún Jèhófà?” MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Máa fi Òtítọ́ Kọ́ni MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Àkànṣe Ìwàásù Láti Pín Ìwé Ìròyìn Ilé Ìṣọ́ Lóṣù September